Our Works and Christ’s Ekklesia

God’s work is everywhere. He has not stopped working since creation. His present work is the building up of His Ekklesia (KJV called it church). It is the vision of God’s eternal purpose which brought Jesus into this world. It is the HOUSE God Himself will dwell. This is a mystery and it is, though right here on earth, but […]

ÌPADÀBỌ̀ ABÌJÀ ÀGBÉDÌDE EKILÉSÍÀ; ÈRÈ ÌṢỌ̀KAN KRISTẸNI

Ọ̀rẹ́ Kristi àti ajogún ìgbàlà bí àwa pẹ̀lú, a fi tayọ tayọ pè iwo pẹ̀lú ṣí àkójọpọ̀ àwọn tí a ti fi oore-ọ̀fẹ́ yàn láti di Ara Kristi (EKILESIA RẸ̀) nínú ayé pàápàá ní agbègbè yìí. Àǹfààní ńlá gbáà ni fún wa láti pè wá kúrò nínú gbogbo làálàá wa gbogbo àti Ìsá sókè sá sódò wa nínú ayé kí […]